Adeboye Adebukola - Apata Ayeraye


By vicky684 Wednesday 24th of July 2024
RRRRRRRR-wizinko.webp
SONG LYRICS

Apata Ayeraye
Ko ma se ja sasan lori mi
Iku Oro Lori igi agbalebu
Ko ma se ja sasan lori mi oo
Oti kikan eso owo eso ese
Ade egun Oko egbe 
Ko ma se ja sofo lori mi

Jesu Jesu 
Apata Ayeraye
Jesu Jesu
Se'bi isadi mi
Je ki omi 
Ohun eje to'nsan 
Lati iha re se iwosan fese mi

Jesu Jesu mi o e
Apata Ayeraye
Ato sa ya ato sa to 
Ato kepe agbani lagba tan o
Oba topo laanu
 Jesu Jesu
Se ibi isadi mi 
Jeki Omi 
Ohun eje to'nsan
Lati iha re se iwosan fese mi

 Ko s'ohun ti mo mu wa
Mo romo agbelebu o
Mo wa ko daso bomi
Emi nwo o fun iranwo
Bi itara mi ko saare 
Tomije mi nsan titi
Ko to s'etutu fese mi
Iwo nikan lole gba mi o
Gba mi lagbatan o 

Jesu Jesu 
Apata Ayeraye
Jesu Jesu
Se'bi isadi mi
Je ki omi 
Ohun eje to'nsan 
Lati iha re se iwosan fese mi

Ese ajogunba
Ese irandiran o
Ese Ile baba iya mi
To ti fi mi sinu ide egun 
Egun ma se rere
Egun ma t'egbe 
Egun ma r'ogo lo
Jesu ro teje re o
Gbami lagbatan o

Ki lole w'ese mi nu
Kosi leyin eje Jesu
Ki lole tun wo mi san
Kosi leyin eje Jesu
Ha eje 'yebiye
To mumi fun bii snow 
Ko si 'sun miran mo
Kosi leyin eje Jesu

Jesu Jesu 
Apata Ayeraye
Jesu Jesu
Se'bi isadi mi
Je ki omi 
Ohun eje to'nsan 
Lati iha re se iwosan

Se iwosan fese mi o(repeat)
Ki ngba ominira pipe
Kin mbo lowo esu ese ataye
Kin njere aye kin forun se're je o
Se iwosan fese mi o
Se iwosan fese mi o

STREAM ON AUDIOMACK